No Description
O je akeko lowolowo bayi ni Ile-eko giga "Imam" ni ilu Riyadh, Saudi Arabia
No Description
Ustaz Abdur Rahman Muhammadul Awwal: O je akekojade ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, o si tun te siwaju fun eko onipokeji ni University of Ilorin, o nse eto eko dokita re lowo bayi ni ile eko giga naa. O ni igbiyanju lori ise ipepe si oju ona....
Akekojade ni ile iwe giga Islamic University ni ilu Madina. Bakannaa ni Sheikh keko ni ile iwe giga yi ti won si gba oye Dokita ninu imo Adiokan esin (Akiida). Won je okan Pataki ninu awon onimimo ni oju ona Al-sunna ni ile Yoruba ati ilu Nigeria lapapo.
Won je okan ninu awon Onimimo ni oju ona sunna (Ahlu-sunna wal-jamaaha) . Won je eni ti o ko eko nipa imo Sharia ni odo awon Aafa ni ilu Nigeria. Won si je okan ninu awon Janmaa sunna ti oruko re nje (Jamaahatu Tadhoomunul Muslimeen). Won ni igbiyanju ti o....
O je akekojade ni ile eko giga Al-imam University ni ilu Riyadh, o si je okan ninu awon onimimo ni oju ona sunna ni ile Yoruba. O tun je oludasile ati olori Jamiyyatul Idaaya ni adugbo Olambe ni ipinle Ogun. O ni igbiyanju ti o po ni oju ona Olohun....
Imran Abdul Majeed Ẹlẹha: O jẹ akẹkọjade ile iwe giga King Saud University ni ilu Riyadh, o si jẹ oludasilẹ Daaru Nai’m Islamic Society, Nigeria. O ni igbiyanju lori ipepe si oju ọna Ọlọhun ni ilana awọn oni Sunna.
Won je okan ninu awon onimimo ni ilana sunna (Ahlus-sunna wal-jamaaha) ni ile Yoruba. Won wa imo ni odo awon alfaa ni ile Nigeria. Won si je alfaa agba ninu ijo sunna kan ti oruko re nje (The Muslim Congress). Won ni igbiyanju ti o po lori ipepe si oju....
Sheikh Abdul-jeleel Alagufon: Won keko jade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je olupepe si oju ona Olohun ni ilana ti Sunna ni ile Yoruba. Won je okan lara awon Jama'tu Tadoomunul Muslimeen.