×
Image

Idajo wiwa iranlowo ni odo awon anabi Olohun ati awon ore Olohun - (Èdè Yorùbá)

Ibeere ti o waye ni aaye yi lo bayi pe: iko kan nso wipe: Ko leto ki a maa wa iranlowo ni odo awon anabi Olohun ati awon ore Olohun, iko miran nso wipe: o leto nitoripe ore Olohun ati aayo Re ni awon eniyan yi, ewo ninu iko mejeeji....

Image

Alaye Itumo Aseju Ninu Esin - (Èdè Yorùbá)

Ibeere nipa itumo aseju ninu esin, awon onimimo se alaye ohun ti o n je aseju ninu esin won si mu apejuwe re wa pelu awon eri.

Image

Idajo Lilo Awon Aaya Al-kurani Fun Iwosan ( Rukya ) - (Èdè Yorùbá)

Fatwa yi je idahun si ibeere ti awon Musulumi maa n beere nipa lilo awon aaya Al-kurani lati fi se iwosan, yala ki eniyan ka a ni tabi ki o han si ori nkan ti o mo ki o si fo o, leyinnaa ki o mu u.

Image

Itumo Ki A ni Agboye Esin Islam Pelu Awon Eri - (Èdè Yorùbá)

Ibeere nipa itumo "O je dandan ki a mo esin Islam pelu awon eri" ninu tira (Al-usuul as- salaasa) ati ibeere miran.

Image

Gbigba Aawe Ninu Gbogbo Awon Ojo Osu Rajab Ati Sha’baan - (Èdè Yorùbá)

Awon eniyan kan maa n gba aawe ninu gbogbo ojo osu Rajab at Sha’baan lehinnaa Ramadan, nje eri wa lori ohun ti won n se yi bi?

Image

Idajọ Nafila ni Ọjọ Alaruba ti o kẹhin ninu Osu Safar - (Èdè Yorùbá)

Idajo esin lori yiyan nafila ni ojo alaruba ti o kehin ninu osu Safar ati idajo esin lori wipe irufe nafila bee adadasile ninu esin ni.

Image

IDAJỌ GBIGBA AAWẸ OSU RAJAB - (Èdè Yorùbá)

Idajo gbigba aawe ninu osu Rajab bi apa kan ninu awon eniyan se maa n se pelu ero wipe osu naa da yato, awon onimimo si ti se alaye wipe adadaale ni gbogbo awon nkan wonyi.

Image

Eni ti o n beru aisan, kinni yoo se? - (Èdè Yorùbá)

Eleyi ni idahun fun ibeere lori bi eniyan kan ba n beru aisan.

Image

AWỌN ADADAALẸ INU OSU RAJAB - (Èdè Yorùbá)

Idahun si ibeere nipa wipe irun ti won n pe ni "solaatur-rogaaibi" ati sise adayanri ojo ketadinlogbon ninu osu Rajab fun awon ijosin kan, se awon nkan wonyi ni ipile ninu esin, idahun si waye wipe adadaale ni gbogbo re je.

Image

Idajo ki eniyan to ni iduro - (Èdè Yorùbá)

Fatwa yi so fun wa nipa bi o ti je wipe eniyan leto lati to ni iduro bi o tile je wipe ipile ni ki eniyan bere nigbati o ba fe to.