Won je akekojade ni ile eko giga Imam University ni ilu Riyadh, won si je oluko ni ile eko giga Al-hikmah University. Won je oludari Al-imaam Ahmad Islamic Centre, won si ni igbiyanju lori ise ipepe si oju ona Olohun ni ilana Sunna.
Sheikh Abdullahi Sayuuti: Akekojade ni ile eko giga Bayero University ni ilu Kano, won si tun keko Diploma ni ile eko giga Islamic University, Republic of Niger. Bakannaa won ko eko ni odo awon onimimo ni ile Nigeria lori imo Tefsiri, Hadiisi ati imo agboye esin. Won je olupepe si....
O je akekojade ni Ile-eko giga "Imam" eka to Mauritania, O si je olupepe si oju ona Olohun ni ilana sunna
O je Akekojade ni ile eko giga ni ilu Medina (Islamic University), o si tun ko eko bi a tise nkoni ni ile eko giga ni ilu Riyadh (King Saud University), lowolowo bayi o je olupepe si oju ona Olohun ati oluko ni ilu Eko.
Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je osise lowolowo ni ile eko giga ti ijoba ni ilu Ilorin. Won je olupepe si oju ona Olohun ni ilana sunna.
Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je oludasile ati oludari ile eko aladani Inayatullahi International Academy ni ilu Iwo. Won je okan ninu awon onimimo ni ilana sunna, won si ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun ati itoju awon omo....
O je akekojade ni ile eko giga ti o wa ni ilu Niger (Islamic University), o si tun ntesiwaju ni ile eko giga ni ilu Riyadh (King Saud)
Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, won si je oludasile ile eko nipa kika ati hiha Alukurani Alaponle. Won ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun ni ilana awon oni sunna, won si ni oripa nibi itoju ati akolekan awon omo Musulumi.
Won je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina. Won si te siwaju fun eko onipogiga (Masters) ni ilu Nigeria. Won je okan ninu awon onimimo ni oju ona sunna ni ile Yoruba. Won si je eni ti o ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun.
O je akekojade ni ile eko giga Al-azhar University, o si tesiwaju fun eko onipokeji ni (International Islamic University) ni ilu Malasia. O je eni ti o ni igbiyanju ni ori ipepe si oju ona Olohun ni ilana sunna.