×
Image

Ojise Olohun Muhammad Ike ni o je fun Gbogbo Aye - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro se alaye bi ojise Olohun anabi Muhammad se je ike fun gbogbo aye, Olohun lo ojise naa lati se agbega fun awon iwa rere O si loo lati pa awon iwa buburu re. Olohun si da ojise re ni eniti o pe ni eda ati ni iwa.

Image

Sise Olohun ni Okansoso ati Awon Ipin Re - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori sise Olohun ni okan soso ati awon ipin re meteeta. Olubanisoro si se alaye ni ekunrere eyi ti o se pataki julo ninu awon ipin wonyi ti opolopo Musulumi ni asiko yi si nse asise ti o fi oju han nibe.

Image

Ajosepo Laarin Awon Musulumi ati Awon ti Won Kiise Musulumi - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa awon nkan kan, ninu won niyi: (1) Musulumi ni eni ti iwa daradara ti Islam pepe si ba han ni ara re. (2) Ninu ohun ti esin Islam pase re ni ki Musulumi maa se aponle gbogbo eniyan, eni ti o je Musulumi ati eni ti....

Image

Agboye Esin Islam - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi so nipa bi esin Islam se je esin ti o dasi igbesi aye eniyan patapata ti kii se nipa ohun ti o nse ninu mosalaasi nikan. Olubanisoro si menu ba itumo Islam, beenaani o so ewu ti o nbe nibi ki eniyan maa tele awon eniyan kan lori....

Image

Iyato ti o wa laarin Itoju Arun ni Ilana Islam ati Oogun Awon Elebo - (Èdè Yorùbá)

Oniwaasi so wipe awon nkan itoju arun ti Olohun se fun awa Musulumi po pupo ju ki a maa wa iranlowo nibi ohun ti o wa lodo awon keeferi ati elebo lo. O si so die ninu awon nkan iwosan naa, gege bi o ti so nipa awon eyi ti....

Image

Pataki Adua - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori adua ati pataki re. Adua ni ohun ti o je oranyan fun Musulumi lati maa se nigbakiigba ti o ba nfe nkan, ki o si doju adua naa ko Olohun re, ki o mase pe elomiran ayafi Oun.