×
Image

Dandan ni fun Musulumi lati maa seri si ibi Al-kurani ati Sunna lori oro Esin - (Èdè Yorùbá)

Fun oriire ni aye yi ati ni orun, oranyan ni fun Musulumi ki o mo wipe Al-kurani ati Sunna ni ohun yoo maa seri si fun gbogbo oro esin re. Eleyi si ni isesi awon eni isiwaju lati ori awon Saabe Ojise Olohun ati awon ti won tele ilana won.....

Image

Kinni o nje Sunna ? - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi so nipa itumo sunna, o si je ki a mo igba ti awon Musulumi bere si pe awon kan ni oni sunna. Ni ipari alaye tun waye lori awon apeere ti a fi maa nda awon oni sunna mo; nitoripe opolopo naa ni won maa npe ara won....