×
Image

Itumọ jijẹ Ojisẹ Ọlọhun ati jijẹ Anọbi Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Alaye lori iyatọ ti nbẹ laarin awọn Anobi ati Ojisẹ Ọlọhun pẹlu ọla ti nbẹ laarin wọn.

Image

Apejuwe Ile Musulumi - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ ti o sọ pataki ile ati bi o se yẹ ki ile musulumi ri.

Image

Iyakuya Ọmọ, ki ni awọn okunfa rẹ - (Èdè Yorùbá)

Awọn idi tabi okunfa ti awọn ọmọ ni awujọ wa loni fi nya alaigbọran

Image

Awọn Ohun ti o maa njẹ ki ọmọ ya alaigbọran - (Èdè Yorùbá)

Diẹ ninu awọn okunfa ipanle, janduku ati aigbọran ti awọn ọmọ ya kalẹ si awujọ. Itẹsiwaju ninu alaye awọn okunfa ipanle pẹlu awọn ọna abayọ si awọn iwa buburu yii.

Image

Ẹsẹ ati Oripa rẹ lori igbesi aye ẹda - (Èdè Yorùbá)

Ohun ti o njẹ ẹsẹ, okunfa rẹ ati oripa ẹsẹ dida lori ẹnikọọkan

Image

Tituuba nibi Ẹsẹ ati awọn majẹmu rẹ - (Èdè Yorùbá)

Alaye lori awọn majẹmu wiwa tituuba lọsi ọdọ Ọlọhun

Image

Suuru ati erenje ti o nbẹ fun un - (Èdè Yorùbá)

Ninu idanilẹkọ yii: (1) Pataki suuru sise. (2) Ọna maarun ti suuru pin si. (3) Ẹsan rere ti nbẹ nibi suuru sise.

Image

Ọsọ Obinrin ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)

Idajọ ti o rọ mọ ọsọ obinrin sise pẹlu ojupọnna ti obinrin le gba se ọsọ ninu Islam

Image

Ninu awọn Iwa Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori awọn Iwa Abiyì ti a le kọ ẹkọ rẹ lati ara Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a]

Image

Awọn Aisedeede ti o maa nsẹlẹ pupọ lori Irun - (Èdè Yorùbá)

Pataki irun kiki ati wipe ohun ni akọkọ ohun ti Musulumi yoo se isiro rẹ ni ọjọ ajinde. Diẹ ninu awọn aisedeede naa gẹgẹ bii: aifarabalẹ, wiwo ọtun wosi lori irun ati bẹẹbẹẹ lọ.

Image

Ẹran ikomọjade ati awọn idajọ ti o rọ mọ ọ - (Èdè Yorùbá)

Alaye ohun ti o njẹ ẹran ikomọjade ati awọn ẹri ti o tọka si i ninu Sunna. Alaye awọn idajọ ẹran ikomọjade pẹlu sisọ awọn majẹmu ti o rọ mọ ọ. Abala yii ni oludanilẹkọ ti jẹ ki a mọ boya a le se ẹran ikomọjade ni ọbẹ, ki a....

Image

Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ - (Èdè Yorùbá)

1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.