×
Image

Iforikanlẹ Itanran Igbagbe lori Irun - (Èdè Yorùbá)

Awọn koko Idanilẹkọ yi: (i) Awọn ohun mẹta ti o maa nse okunfa iforikanlẹ itanran igbagbe lori Irun. (ii) Awọn aaye ti a ti maa nse iforikanlẹ itanran igbagbe, siwaju salamọ ni tabi lẹyin salamọ. (iii) Awọn idajọ ti o rọ mọ iforikanlẹ itanran igbagbe.

Image

Ọla ti nbẹ fun kika Alukurani Alapọnle - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yi sọ nipa ohun ti a npe ni Alukuraani pẹlu awọn ẹri lati inu ayọka rẹ, ọrọ si tun waye lori awọn ọla ti o wa fun kika rẹ ati awọn ẹkọ ti o rọ mọ kike rẹ.

Image

Awọn Ojuse Musulumi si ara wọn - (Èdè Yorùbá)

Ibanisọrọ yii sọ daradara ti o yẹ ki o maa ti ọwọ musulumi kan jade si ọdọ musulumi keji ati awọn aburu ti o yẹ ki wọn maa le jina si ara wọn.

Image

Ibẹru Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Koko idanilẹkọ yii da lori awọn nkan mẹta wọnyii: (i) Ọla ti nbẹ fun ibẹru Ọlọhun, (ii) Pataki ibẹru Ọlọhun, (iii) Anfaani ti o wa nibi bibẹru Ọlọhun.

Image

Ajọse ti ọmọ Iya ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori awọn koko mẹta wọnyii: (i) Pataki asepọ jijẹ ọmọ iya ninu ẹsin. (ii) Ẹsan ti o wa fun asepọ ọmọ iya ninu ẹsin. (iii) Awọn nkan ti o maa nba jijẹ ọmọ iya ninu ẹsin jẹ.

Image

Iwọ Aladugbo - (Èdè Yorùbá)

1- Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ aladugbo pẹlu itọka rẹ lati inu Alukurani, bakannaa ọrọ tun waye lori diẹ ninu awọn iwọ aladugbo gẹgẹ bii ki Musulumi jẹ ki ọkan aladugbo rẹ balẹ, ki o ma je ki suta tabi aburu wa lati ọwọ rẹ si aladugbo rẹ. 2- Itẹsiwaju....

Image

Ikẹ ati Aanu sise ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)

1- Alaye wa ninu idanilẹkọ yii lori: (1) Itumọ ikẹ ati aanu gẹgẹ bi awọn onimimọ ẹsin se se alaye rẹ. (2) Diẹ ninu awọn agbegbe ti ikẹ ati aanu ti gbodo maa waye gẹgẹ bii ki olori se ikẹ fun awọn ọmọlẹyin rẹ ati sise aanu fun awọn ọmọde.....

Image

Aluwala Oniyagbẹ (At-Tayammum) - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori idajọ aluwala oniyagbẹ (at-tayammum), ati wipe nigba wo ni a le se e ati bi a se nse e.

Image

Awọn Ekọ ti o rọ mọ sise Igbansẹ (Itọ ati Igbẹ) - (Èdè Yorùbá)

Alaye lori awọn ekọ ati awọn ohun ti o je dandan fun musulumi lati se nigbati o ba fẹ se igbansẹ, ọrọ si tun waye lori awọn aaye ti a kọ fun ni lati se igbansẹ si.