×
Image

Alaye Lori Sunna Ati Pataki Re Nibi Agboye Esin - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro se ni alaye lekunrere nkan ti won npe ni Sunna, o so pelu akori wipe odidi esin Islam ni Sunna atipe Sunna gan an ni esin Islam. O tesiwaju ninu alaye re wipe agboye Alkurani ko rorun fun Musulumi bikose latari Sunna, bee si ni Sunna je aayan ongbifo....

Image

Awon Asa ti o tako Sunna - (Èdè Yorùbá)

Olubanisọrọ se alaye awọn idajọ ẹsin ti o rọ mọ mima jẹ orukọ ẹlomiran ti o yatọ si baba ẹni, ati pipe apemọra nkan ti kii se ti ẹni (gẹgẹ bii imọ, dukia ati bẹẹ bẹẹ lọ). O si tun sọ nipa ewu ti o nbẹ nibi pipe musulumi kan....

Image

Alaye Awon Hadiisi nipa Gbigba Iwaju Eni ti o ba n ki Irun koja ninu Tira “Umdatul Ahkaam” - (Èdè Yorùbá)

Idanileko yi so alaye gbogbo awon idajo ti o ro mo gbigba iwaju eni ti o ba n ki irun koja, yala eni ti o fi nkan si iwaju re tabi eni ti ko fi nkankan si iwaju.

Image

Alaye Hadiisi Nipa Idajo Nkan Osu Obinrin Ninu Tira Umdatul Ahkaam - (Èdè Yorùbá)

Eyi ni alaye awon Haadisi tinso nipa Eje Nkan Osu Obinrin lati inu tira ‘Umudatul Haakaam’, ti olubanisoro si s’alaye awon idajo esin ti o ro mo.

Image

Alaye lori Awon Hadiisi ti o so nipa Gbigba Aawe ni ori Irinajo ninu tira Umdatul Ahkaam - (Èdè Yorùbá)

Idanileko yi so nipa awon eko ti Islam gbe kale fun eniti o ba ngba aawe gege bii yiyara fun isinu ati lilora lati je saari, bakannaa ni oludanileko tun so oro nipa asiko ti aawe maa nbere ati asiko ti o maa npari, o si tun so nipa bi....

Image

Alaye Hadiisi ti o so nipa Itanran eniti o ni Ajosepo Pelu Eleto Re ni Osan Ramadan - (Èdè Yorùbá)

Koko idanileko yi ni oro nipa itanran ti o nbe fun eni ti o ni ajosepo pelu eleto re ni osan Ramadan, oniwaasi se alaye re ni ekunrere o si tun menu ba awon idajo miran.

Image

Alaye Itumo Awon Hadiisi ti o so nipa Irun Pipe ninu tira Umdatul Ahkaam - (Èdè Yorùbá)

Idanileko yi so nipa awon idajo esin ti o ro mo irun pipe, oniwaasi so oro nipa re ni ifosiwewe nigbati o nse alaye awon hadiisi ti o ro mo o.

Image

Alaye Hadiisi ti o so nipa Sakaatu Fitri ninu tira Umdatul Ahkaam - (Èdè Yorùbá)

Eleyi ni itumo awon hadiisi kan ti o so nipa sakaatul fitri ti awon Yoruba npe ni jaka. Oniwaasi se alaye awon idajo esin ti o ro mo o gege bii awon ti o ye ki o yo o, irufe ounje ti a fi maa nyo o ati odiwon ti....