×
Image

Aseju ninu Ẹsin -2 - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ nipa awọn okunfa aseju ninu ẹsin ati awọn ohun ti o le dẹkun tabi fi opin si sise aseju ninu ẹsin Islam.

Image

Aseju ninu Ẹsin -1 - (Èdè Yorùbá)

Alaye ohun ti njẹ aseju ninu ẹsin, ipilẹ ati paapaa aseju ninu ẹsin ati awọn apejuwe rẹ.

Image

Ọla ati Ipo ti o wa fun Awọn Saabe Ojisẹ Ọlọhun (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a)- 3 - (Èdè Yorùbá)

Awọn imọran fun gbogbo Musulumi lori bi igbiyanju si oju ọna ẹsin yoo se maa tẹsiwaju ni ohun ti wọn fi kadi eto nilẹ.

Image

Ọla ati Ipo ti o wa fun Awọn Saabe Ojisẹ Ọlọhun (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a)- 2 - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ waye ninu apa keji yii lori: (1) Iwọ ti o yẹ ki awa Musulumi maa pe fun awọn saabe Anabi. (2) Awọn ẹri ti o fi ẹsẹ mulẹ lori wipe ko si ede aiyede laarin awọn ara ile Anabi ati awọn Saabe yoku.

Image

Ọla ati Ipo ti o wa fun Awọn Saabe Ojisẹ Ọlọhun (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a)- 1 - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohun ti o waye ninu apa yii: (1) Itumọ Saabe ninu ede larubawa ati wipe taani awọn Saabe gẹgẹ bi awọn onimimọ se se apejuwe wọn. (2) Ipo ati ọla ti nbẹ fun awọn Saabe pẹlu ẹri rẹ lati inu Sunna.

Image

Adua ati Iranti Olohun ni ona ti o to - 2 - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro tesiwaju pelu sise alaye awon asiko ti adua ma ngba, o si tun menuba awon nkan ti kii je ki adua gba, o wa se akotan ibanisoro re pelu awon nkan ti Yoruba ti ro po mo adua.

Image

Adua ati Iranti Olohun ni ona ti o to - 1 - (Èdè Yorùbá)

Ohun ti ibanisoro yi da le lori ni oro nipa adua, olubanisoro se alaye awon ohun ti a npe ni eko adua ti o tumo si awon nkan ti o maa nse okunfa gbigba adua.

Image

Sise Daadaa si Awon Obi Mejeeji ati Ikilo lori sise aburu si won - (Èdè Yorùbá)

Sise daadaa si awon obi je ojuse Pataki ti Olohun pa omo ni ase re leyin ti o pase wipe ko gbodo josin fun nkan miran yato si Oun Olohun. Eleyi ni ohun ti ibanisoro yi da lelori, olubanisoro si mu awon apejuwe lori oore ti o wa ninu ki....

Image

Adua ati Asikiri - (Èdè Yorùbá)

1- Itumọ adua ati asikiri lati inu agbọye Alukuraani ati Sunnah pẹlu alaye lori ẹkọ adua ati asikiri ni sise. 2- Pataki adua, asiko gbigba adua ati gbogbo ohun ti o takọ ilana gbigbaa adua ni sise.