×
Image

Alaye Lori bi Anabi se maa nse Aluwala - (Èdè Yorùbá)

Idanileko yi je alaye lori hadiisi eleekeje ninu tira “Umdatul Ahkaam”, koko oro idanileko naa ni alaye nipa bi ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o o maa ba a- se maa nse aluwala.

Image

Alaye Lori Awon Iruju ti o nbe fun Awon Eniyan Kan nipa Wiwa Ategun (At-tawassul) - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori alaye ni ekunrere lori awon iruju ti o nbe fun awon eniyan kan nipa awon ohun ti o leto ki Musulumi maa fi se ategun si odo Olohun ati awon nkan ti ko leto nigbati o ba npe Olohun.

Image

Lilo Sunna Laarin Aseju ati Aseeto Lodo Awon Odo - (Èdè Yorùbá)

Ibanisọrọ yii da lori sise aseju tabi aseeto ninu ẹsin eyi ti o wọpọ laarin awọn ọdọ, ti olubanisọrọ si jẹ ki a mọ awọn okunfa rẹ gẹgẹ bii: 1-Aini imọ ẹsin ti o kun to, 2-Agbọye odi lori ẹsin, 3-lilero aburu si awọn onimimọ, 4-Igbarata ẹsin, 5- Sisọ gbogbo....

Image

Bi Ojise Olohun ti ko Awon Saabe re ni Eko - (Èdè Yorùbá)

Oro lori bi Annabi- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- se ko awon Sahabe re ni eko ti aye won fi dara ti orun won naa si rorun.

Image

Adua ati Asikiri - (Èdè Yorùbá)

1- Itumọ adua ati asikiri lati inu agbọye Alukuraani ati Sunnah pẹlu alaye lori ẹkọ adua ati asikiri ni sise. 2- Pataki adua, asiko gbigba adua ati gbogbo ohun ti o takọ ilana gbigbaa adua ni sise.

Image

Itumo Igberaga - (Èdè Yorùbá)

Alaye ohun ti a n pe ni igberaga ohun naa ni ki eniyan maa se atako ododo ti o fi oju han ati yiyepere awon eniyan miran.