×
Image

Alaye Awọn Opo Islam Maraarun - (Èdè Yorùbá)

Alaye ọrọ lori awọn opo ẹsin Islam maraarun pẹlu bi ikọọkan wọn se ni ipan to ati ewu ti o wa ninu fifi ọwọ yẹpẹrẹ mu wọn.

Image

Igbagbo Ododo - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori igbagbo ninu Olohun ati alaye itumo re. Olubanisoro yi se alaye pupo lori itumo ohun ti o nje igbagbo, o si fi awon apeere laakaye ba awon eniyan soro pupo nibe nitoripe eleyi ni o ba awon ogooro eniyan ti won wa ni ijoko naa mu.....

Image

Nini Igbagbo si Ojo Ikehin - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro se alaye lekunrere ohun ti a npe ni Ojo Ikehin ati awon orisirisi oruko ti Olohun Allah fun un ninu Alukuraani, Olubanisoro si tun se alaye awon nkan ti Ojo Igbehin ko sinu.

Image

Ẹsẹ ati ilapa rẹ lori ọmọniyan ati awujọ - 2 - (Èdè Yorùbá)

Abala yii kun fun ibeere ati idahun.

Image

Ẹsẹ ati ilapa rẹ lori ọmọniyan ati awujọ - 1 - (Èdè Yorùbá)

"[1] Awọn aburu ti ẹsẹ maa nse okunfa rẹ fun ẹnikọọkan ati awujọ. [2] Gbogbo idaamu ti o ba aye loni wa latara ẹsẹ dida".

Image

Oju-ona si Ogba Idera (Al-janna) - 2 - (Èdè Yorùbá)

Oniwaasi se alaye ni abala yi wipe ti awon onimimo esin ba nso oro nipa awon ijo ti yoo la ti yoo ba ojise Olohun wo Al-janna itumo re ni wipe awon ti won ba ntele ilana ojise naa, kiise gbogbo eniti o ba npe ara re ni oni sunna,....

Image

Oju-ona si Ogba Idera (Al-janna) - 1 - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi da lori awon nkan ti yo maa je atona fun Musulumi losi ogba idera Al-janna, alakoko re ni adiokan ti o dara ti o jinna si ebo, eleekeji si ni ijosin ti o ni alaafia ti o wa ni ibamu pelu eyi ti ojise Olohun se.

Image

Iroyin Awon Omo Alujanna Ati Iroyin Awon Omo Ina - (Èdè Yorùbá)

Oro nipa ise ti awon omo Alujanna yoo maa se ni ile aye ati iroyin won bakannaa ise ti awon omo ina yoo maa se ni ile aye ati awon iroyin won.

Image

Asa ati Ẹsin - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ ti o n se alaye awọn nkan ti o n ba ẹsin jẹ mọ Musulumi lọwọ ti apa kan ninu awọn eniyan si n pe ni asa.

Image

Aburu Iwa Agbere ( Sina ) - 2 - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ nipa awọn okunfa iwa agbere (sina) ati idahun si awọn ibeere.

Image

Aburu Iwa Agbere ( Sina ) - 1 - (Èdè Yorùbá)

"[1] Alaye ohun ti o njẹ iwa agbere ati wipe isẹ buburu ti Ọlọhun korira ni. [2] Diẹ ninu awọn oniranran aburu ti o rọ mọ iwa agbere.".

Image

Oro Nipa Awon Alujannu - 2 - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro tun se alaye nipa bi awon alujannu se maa nlo awon eniyan ti won ba gbe ara won si ipo eniti won yoo maa ke pe ti won yoo si maa gbe aworan won wo lati fi so awon eniyan nu. Ni ipari, olubanisoro yi so nipa awon ona....