×
Image

Itọju Awọn Obi - (Èdè Yorùbá)

[1] Asọtẹlẹ lati ọdọ Ọlọhun Allah ni sise daada si obi ẹni. [2] Alukuraani ati ẹgbawa hadisi sọ nipa pataki daada sise si awọn obi mejeeji. [3] Apẹẹrẹ oniran-nran daada ti eniyan le maa se si awọn obi rẹ. [4] Awọn ojuse ọmọ si obi pẹlu awọn apejuwe ifisisẹse rẹ....

Image

Ajosepo Laarin Awon Musulumi ati Awon ti Won Kiise Musulumi - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa awon nkan kan, ninu won niyi: (1) Musulumi ni eni ti iwa daradara ti Islam pepe si ba han ni ara re. (2) Ninu ohun ti esin Islam pase re ni ki Musulumi maa se aponle gbogbo eniyan, eni ti o je Musulumi ati eni ti....

Image

Pataki Adua - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori adua ati pataki re. Adua ni ohun ti o je oranyan fun Musulumi lati maa se nigbakiigba ti o ba nfe nkan, ki o si doju adua naa ko Olohun re, ki o mase pe elomiran ayafi Oun.

Image

Itoju Awon Obi Mejeeji - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa pataki sise daradara si awon obi mejeeji ati bi Olohun ti se e ni dandan fun omo eniyan, beeni o tun se alaye esan nla ti o wa nibi ki eniyan maa se itoju won ati aburu ti o wa nibi sise aidaa si won.

Image

Iwọ Awọn Alabagbe - 2/2 - (Èdè Yorùbá)

Apẹrẹ sise daadaa si alabagbe ẹni lati ọdọ awọn Sahabe Anabi ati awọn ẹni-rere isaaju ninu Islam.

Image

Iwọ Awọn Alabagbe -1/2 - (Èdè Yorùbá)

Itumọ alabagbe ati awọn ẹri lori bi o ti se pataki ki Musulumi maa se daadaa si alabagbe lati inu Alukuraani ati sunna.

Image

Dida Ebi Po - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro se alaye ohun ti o nje ebi, o si se alaye bakannaa bi o se ye ki eniyan maa da ebi re po. O tun se afikun anfaani ti o wa nibi ki eniyan maa da ebi po ati ijiya ti o wa nibi ki eniyan maa ja okun....