×
Image

Die Ninu Awon Ewa Islam - (Èdè Yorùbá)

1- Oro waye ninu waasi yi lori Itumo gbolohun Islam ati alaye bi o se je wipe ijosin Ojise Olohun, iwa re ati ise re je apejuwe ti o daju fun itumo paapaa esin Islam. Oro si tun waye lori bi ’waayi’ se maa n so kale fun Ojise Olohun.....

Image

Itosona Lori Asigbo Esin - (Èdè Yorùbá)

1- Ibanisoro yii da lori awon ona abayo si asigbo esin ti o gbaye kan laarin awon Musulumi. 2- Ibanisoro je afikun lori awon okunfa ati ona abayo si awon asigbo tabi aseju ninu esin.

Image

Majemu Pipe Eniyan kan ni Keferi - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yii da lori awon majemu ti a gbodo ri lara musulumi kan ki a to le pe ni Keferi, ti Olubanisoro si bere pelu nkan ti pipe Musulumi kan ni keferi tumo si ninu Islam.

Image

Awon Alaye Esin Nipa Igbagbo si Ayanmon (Kadara) - (Èdè Yorùbá)

Idanileko yi so nipa awon nkan wonyi: (1) Itumo Ayanmo. (2) Gbigba ayanmo ni ododo je okan ninu awon origun igbagbo. (3) Olohun ti O da awa eda ni O da awon ohun ti a n se ni ise. (4) Awon ipele Ayanmo. (5) Ninu awon idi ti Olohun fi....

Image

Itumo Ki Oko o Ko Iyawo re Sile ati Awon Aburu ti o Wa Nibe - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi mu idahun wa lori awon ibeere wonyi: Kinni itumo tolaaki ati itumo Khulkhu, agbara wo ni ile ejo ni lati se onpinya laarin oko ati aya atipe kinni aburu ti o wa nibi ki onpinya sele laarin oko ati aya.

Image

Eto Oko ati Aya ninu Islam - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro se alaye awon eto wonyi: (i) Eto oko lori aya, (ii) Eto Aya lori oko, (iii) Eto ti awon mejeeji ni si ara won.

Image

Awon Iroyin Jije Eni Olohun - (Èdè Yorùbá)

Oniwaasi so wipe awon majemu meta kan wa fun jije eni Olohun (i) Ki eniyan so asepo laarin ara re ati Olohun re (ii) Ki o so asepo laarin oun ati emi ara re (iii) Ki o so asepo laarin oun ati awujo re.