×
Image

Awon Janmoo Islam: Oore ti o nbe lara won ati ibi ti won ku si - (Èdè Yorùbá)

Awon janmoo Islam ti o wa ni awujo ni anfaani pupo, awon ni won nse itoju awon omo Musulumi ti won ko je ki opolopo won ti sina tabi di keferi, won maa nse alaye esin fun awon omode ati odo ati agbalagba, bibe won ni awujo si je amin....