×
Image

Ojuse Olori ati Awon ti won n dari ninu Islam - 1 - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa bi o ti je wipe esin Islam menu ba gbogbo nkan patapata ti o fi de ibi eko bi a ti se n to tabi ya igbe, bawo ni Islam kose wa ni so nipa eto bi a se ndari ilu ati bi a se nse....

Image

Awon Ohun ti o je Ojuse Eni ti o sese gba Esin Islam - (Èdè Yorùbá)

Oniwaasi so Pataki esin Islam o si je ki awon eniyan mo wipe gbigba esin Islam kiise mimoose enikan bikose aanu Olohun lori eni naa. Bakannaa o tun so iyato ti o wa laarin Islam ati awon esin yoku, ti o si so awon majemu ti o maa nje ki....

Image

Ola Ti O Nbe Nibi Irun Kiki Ati Awon Anfaani Re - (Èdè Yorùbá)

Oore ti o po pupo ni o wa nibi irun kiki fun Musulumi. Ohun ni ona ti o dara julo lati wa asunmo si odo Olohun, o si maa nse okunfa aforiji fun Musulumi, bakannaa ni o je oluranlowo fun erusin lati wo ogba idera (al-Jannah).

Image

Ọranyan Aluwala ati Ohun ti o nba a jẹ - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa awọn ọranyan aluwala, ati awọn ohun ti a fẹ ki Musulumi se ninu aluwala ati awọn ohun ti o nba aluwala jẹ.

Image

Ọla ti o nbẹ fun Aluwala ati bi a ti se nse e - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori alaye bi a se nse aluwala ati awọn ẹsan (ọla) ti o nbẹ fun aluwala sise, bakannaa ọrọ nipa awọn ohun ti o nsọ aluwala di ọranyan fun musulumi.

Image

Bi a ti se nwẹ Iwẹ Ọranyan (Al-Guslu) - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ waye lori awọn nkan marun ti o maa nsọ iwẹ di dandan fun ni lati wẹ, alaye si tun waye ni soki lori bi a se le wẹ iwẹ naa.

Image

Ipo Irun Ninu Islam - (Èdè Yorùbá)

Akosile yi so nipa bi irun kiki ti se pataki to ninu esin Islam, ohun ni origun ti o lola julo leyin ijeri mejeeji, ohun naa si ni ise ti erusin maa n se ti o loore julo leyin won.

Image

Gbigba Awe Ramadan - (Èdè Yorùbá)

Gbigba Awe Ramadan

Image

Yiyo Zakaat - (Èdè Yorùbá)

Yiyo Zakaat

Image

Lilo Si Ile Oluwa - (Èdè Yorùbá)

Lilo Si Ile Oluwa

Image

Alaye Lori bi Anabi se maa nse Aluwala - (Èdè Yorùbá)

Idanileko yi je alaye lori hadiisi eleekeje ninu tira “Umdatul Ahkaam”, koko oro idanileko naa ni alaye nipa bi ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o o maa ba a- se maa nse aluwala.