×
Image

Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 3/ 3 - (Èdè Yorùbá)

Awọn ọna abayọ kuro ninu adanwo.

Image

Alaye Nipa Eto Isejoba Aye Titun ati Aburu ti o wa nibe fun Awa Musulumi - (Èdè Yorùbá)

Koko ohun ti ibanisoro yi da le lori ni: (1) Eto isejoba aye titun ni aburu ti yoo se fun awon ilu Musulumi, nibi eto oro-aje won ati awujo won. (2) Ohun ti oore aye ati ti orun wa nibe fun awa Musulumi ni ki a maa lo ofin Olohun....

Image

Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 2/ 3 - (Èdè Yorùbá)

Adanwo ti o ba awọn Anọbi Ọlọhun, anfaani ti o wa nibi ki Ọlọhun fi adanwo kan Musulumi ati Okunfa adanwo.

Image

Adanwo: Itumọ rẹ ati bi Musulumi yoo se se pẹlu rẹ 1/ 3 - (Èdè Yorùbá)

Itumọ adanwo ati orisirisi awọn aworan ti o maa ngba kan ọmọ’niyan.

Image

ORO NIPA AWON MALAIKA - (Èdè Yorùbá)

Oro waye ninu waasi yi lori itumo Malaika, ohun ti a gba lero pelu ki Musulumi ni igbagbo si Malaika, awon nkan ti Olohun fi sa won lesa ati wipe orisirisi ni won je.

Image

IRIN AJO TI KO SE YE (IRIN AJO IKU) - (Èdè Yorùbá)

Oro nipa iku ati bi a se n we oku ni ilana esin Islam, pelu itoka si die ninu awon ohun ti o je dandan ki Musulumi ni igbagbo si lehin iku.

Image

ORO NIPA ESIN ISLAM NI ILE YORUBA - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa awon asigboye esin ni odo awon iran Yoruba ti won da asa won po mo esin ti o si je wipe awon asa naa tako ohun ti esin Islam mu wa. Oniwaasi si menu ba awon asa ati ise kan ti o je wipe ebo sise....

Image

Taani Awọn ti wọn n sọ wipe Alukuraani nikan ni Awọn ni Igbagbọ si? - 3 - (Èdè Yorùbá)

Idahun si iruju awọn ti wọn n sọ wipe Alukuraani nikan ni awọn ni Igbagbọ si (Al-Kur’aniyuun).

Image

Taani Awọn ti wọn n sọ wipe Alukuraani nikan ni Awọn ni Igbagbọ si? - 2 - (Èdè Yorùbá)

Alaye lori ibasepọ Sunnah ati Alukuraani, anfaani Sunnah nibi igbagbọye Alukuraani ati idahun si iruju awọn ijọ yii.

Image

Taani Awọn ti wọn n sọ wipe Alukuraani nikan ni Awọn ni Igbagbọ si ? - 1 - (Èdè Yorùbá)

Alaye awọn ti wọn n sọ wipe Alukuraani nikan ni awọn ni Igbagbọ si. Kinni adisọkan wọn? Bawo ni awọn ijọ yii se sẹ yọ, ta si ni olori wọn

Image

Alaye Aaya kẹjọ ati ẹkẹsan ninu Suuratul Mumtahinah - (Èdè Yorùbá)

Ohun ti o waye ninu ibanisọrọ yii: (1) Sise daadaa si aladugbo ti kiise Musulumi. (2) Ki ọmọ maa se daadaa si awọn obi rẹ mejeeji ti wọn kiise Musulumi.

Image

Ifeto si Ọmọ Bibi, Ifopin si Ọmọ Bibi, ati Oyun Sisẹ - 3 - (Èdè Yorùbá)

Eyi ni abala ti o kun fun ibeere ati idahun, ti awọn ọrọ olowo-iye-biye si ti ibẹ yọ.