×
Image

Orukọ Ọlọhun ( Al-Malik ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Malik ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 3 - (Èdè Yorùbá)

Idajọ ẹni ti o n se oogun ẹbọ ni wọn se alaye rẹ ni abala yii.

Image

Sise Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ - (Èdè Yorùbá)

1- Awọn akori ọrọ ti o jẹyọ ni abala yii ni wọnyii: (i).Itumọ sise Ọlọhun ni Ọkan soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ. (ii). Alaye lori awọn ti wọn lodi si Sunna nibi ilana yii. 2- Alaye nipa ilana awọn ti won tẹle Sunna nibi orukọ Ọlọhun ati....

Image

Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ - (Èdè Yorùbá)

1- Itan Iya Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ati itan iya-iya rẹ. 2- Alaye bi wọn se ni oyun Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọna iyanu pẹlu bibi rẹ ni ọna iyanu, ti eleyi ko si sọ....

Image

Orukọ Ọlọhun ( Ad-Dayyaan ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Ad-Dayyaan ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Alaye nipa Ẹjẹ nkan-osu Obinrin, Ẹjẹ Awọọda ati Ẹjẹ Ibimọ - (Èdè Yorùbá)

Alaye ati idajọ lori ohun ti o nii se pẹlu Ẹjẹ Alaada (nkan-osu Obinrin). Idanilẹkọ ni abala yii da lori alaye ati idajọ ti o rọ mọ Ẹjẹ Awọọda ati Ẹjẹ Ibimọ.

Image

Orukọ Ọlọhun ( Al-Waarith ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Waarith ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 2 - (Èdè Yorùbá)

Alaye lẹkunrẹrẹ lori idajọ oogun ti o ni ẹbọ ninu pẹlu awọn apẹẹrẹ rẹ.

Image

Iyato ti o wa laarin Itoju Arun ni Ilana Islam ati Oogun Awon Elebo - (Èdè Yorùbá)

Oniwaasi so wipe awon nkan itoju arun ti Olohun se fun awa Musulumi po pupo ju ki a maa wa iranlowo nibi ohun ti o wa lodo awon keeferi ati elebo lo. O si so die ninu awon nkan iwosan naa, gege bi o ti so nipa awon eyi ti....

Image

Pataki sise Isẹ tọ Imọ - (Èdè Yorùbá)

Alaye erenjẹ ti o wa fun lilo Imọ ati Ibalẹjọ ti o wa fun ki eniyan ma lo Imọ.

Image

Orukọ Ọlọhun ( Al-Qọyyuum ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Qọyyuum ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 1 - (Èdè Yorùbá)

Alaye idajọ Islam lori oogun iwosan – ewe ati egbo ati awọn nkan miran ti o jẹ iwosan fun ọmọniyan.