×
Image

Itumọ Sise Aimoore si Ọlọhun ( Allah ) ati Ipin rẹ - (Èdè Yorùbá)

Itumọ sise Aimoore si Ọlọhun (Allah) ati awọn ọna ti o pin si pẹlu iyatọ ti o n bẹ laarin kufuru Nla ati kufuru keekeeke.

Image

Gbigba Kadara gbọ - (Èdè Yorùbá)

Itumọ igbagbọ si kadara pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah. Lẹyin naa idahun waye si ibeere yi: “ Njẹ a le fi kadara se ikẹwọ fun ẹsẹ dida bii?”

Image

Igbagbọ si Awọn Ojisẹ Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Ninu idanilẹkọ yii: (i) Itumọ nini igbagbọ si awọn Ojisẹ Ọlọhun pẹlu ẹri rẹ lati Shẹriah, (ii) Pataki awọn Ojisẹ Ọlọhun ati bukaata wa si wọn.

Image

Pataki Adiọkan ti o Yanju - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ nipa awọn ipilẹ adiọkan Musulumi, pataki mimọ amọdaju rẹ, lilo lati fi se isẹ se ati ipepe lọ sibẹ

Image

Sise asalaatu fun Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] - (Èdè Yorùbá)

1- Alaye nipa aayah Alukuraani ti o wa lori asalaatu sise fun Anọbi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a], pataki asalaatu ati wipe bawo ni o se yẹ ki a maa se. 2- Pataki sise asalaatu fun Anabi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a]....

Image

Alaye nipa Ijọ Shii’ah - (Èdè Yorùbá)

1- Alaye nipa awọn ijọ ti njẹ Shii’ah ati wipe ki ni adisọkan wọn nipa Ọlọhun ati si Alukuraani 2- Igbagbọ ijọ Shii’ah si awọn Sahabe ati ipo ti wọn gbe awọn asiwaju wọn si 3- Alaye diẹ ninu awọn adisọkan wọn gẹgẹ bii:- Tukyah, Muta’h. Ti oludanilẹkọ si tun....

Image

Orukọ Ọlọhun ( Al-Maliik ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Maliik ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Orukọ Ọlọhun ( Al-Maalik ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Maalik ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Orukọ Ọlọhun ( Al-Malik ) - (Èdè Yorùbá)

Awọn ohunatiaworanniede Yoruba pẹluakọle: [Awọn OrukọỌlọhunti O Rẹwajulọni sisẹ n tẹle], niapayiini a tiriOrukọỌlọhun [ Al-Malik ], pẹlu awọn itumọti O n tọkasi, ọnaakọsilẹ rẹsidaraniriri.

Image

Iyatọ laarin Oogun ti o ba Islam mu ati Idan - 3 - (Èdè Yorùbá)

Idajọ ẹni ti o n se oogun ẹbọ ni wọn se alaye rẹ ni abala yii.

Image

Sise Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ - (Èdè Yorùbá)

1- Awọn akori ọrọ ti o jẹyọ ni abala yii ni wọnyii: (i).Itumọ sise Ọlọhun ni Ọkan soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ. (ii). Alaye lori awọn ti wọn lodi si Sunna nibi ilana yii. 2- Alaye nipa ilana awọn ti won tẹle Sunna nibi orukọ Ọlọhun ati....

Image

Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a], bi Alukuraani ti se iroyin rẹ - (Èdè Yorùbá)

1- Itan Iya Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ati itan iya-iya rẹ. 2- Alaye bi wọn se ni oyun Anọbi Isa [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] ni ọna iyanu pẹlu bibi rẹ ni ọna iyanu, ti eleyi ko si sọ....