×
Image

Gbigba Kadara gbo - (Èdè Yorùbá)

Akole yi so nipa bi o ti se je ojuse Musulumi ki o so enu aala Olohun nigba ti o ba n wa arisiki, ki o ma gba ona haraam ti Olohun ko fe lati fi wa oro. Ki o ma fi ibinu Olohun wa iyonu awon eniyan.

Image

Pataki titele Sunna Anobi Muhammad - (Èdè Yorùbá)

Oludanileko ninu eto yii soro nipa bi o ti se Pataki fun Musulumi ki o maa tele Sunna Anobi wa Muhammad

Image

Ola ti o wa fun Eni ti o ba mo Olohun lokan - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi je ki a mo Pataki ki Musulumi mo Olohun re ni okan soso ki o si doju ijosin ko Olohun naa. Mimo Olohun ni okan (Taoheed) ni ipile esin, ohun si ni ohun ti o ye ki Musulumi moju to julo.

Image

Sise Daadaa si Awon Obi Mejeeji ati Ikilo lori sise aburu si won - (Èdè Yorùbá)

Sise daadaa si awon obi je ojuse Pataki ti Olohun pa omo ni ase re leyin ti o pase wipe ko gbodo josin fun nkan miran yato si Oun Olohun. Eleyi ni ohun ti ibanisoro yi da lelori, olubanisoro si mu awon apejuwe lori oore ti o wa ninu ki....

Image

Eko nipa Odun Itunu Aawe - (Èdè Yorùbá)

Olohun se ipari aawe ati ojo kewa osu Dhul-hijja ni odun fun awa Musulumi. Ibani soro yi n so nipa awon eko ti Islam ko wa nipa odun aawe. Ninu re ni ki Musulumi wo aso ti o dara ti o si wuyi ni ojo odun lati gbe ojo yi....