×
Image

Idajo ati Aworan Kikọse Awọn Keferi - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii jẹ ki a mọ awọn orisi ọna ti awọn Musulumi fi maa nkose awọn ẹlẹsin miran pẹlu awọn eri lati inu Alukuraani ati awọn ẹgbawa hadisi ti o nkọ fun Musulumi lori mima kọse awọn ẹlẹsin miran.

Image

Alaye Nipa Eto Isejoba Aye Titun ati Aburu ti o wa nibe fun Awa Musulumi - (Èdè Yorùbá)

Koko ohun ti ibanisoro yi da le lori ni: (1) Eto isejoba aye titun ni aburu ti yoo se fun awon ilu Musulumi, nibi eto oro-aje won ati awujo won. (2) Ohun ti oore aye ati ti orun wa nibe fun awa Musulumi ni ki a maa lo ofin Olohun....