×
Image

Idajọ ki Musulumi jẹ Ẹran ti Yahudi ati Nasara ba pa - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ ti o se alaye: (1) Idajọ ẹran ti Musulumi ba pa, yala o da orukọ Ọlọhun si ni tabi ko da orukọ Ọlọhun si ni latari igbagbe. (2) Idajọ Ẹran ti Yahudi tabi Nasara ba pa yala fun ọdun ni tabi fun nkan miran. (3) Idajọ gbogbo ẹran ti....

Image

Ifọrọwọrọ Laarin Musulumi Ati Kristiani - (Èdè Yorùbá)

Iwe yii je iforowero laarin eni ti o se e ati awon alagba kan ninu esin Kristiani