×
Image

Idajọ Irun ti a maa nki nigbati Ọsan ba di Oru (Sọlaatul-Kusuuf) - (Èdè Yorùbá)

Alaye waye ninu waasi yi nipa bi Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ti se ki irun bi osan ba di oru ni oju aye re pelu awon idajo irun yii. Oro si tun waye lori wipe oorun ati osupa ninu awon amin agbara Olohun....