×
Image

Itumo Ki Oko o Ko Iyawo re Sile ati Awon Aburu ti o Wa Nibe - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi mu idahun wa lori awon ibeere wonyi: Kinni itumo tolaaki ati itumo Khulkhu, agbara wo ni ile ejo ni lati se onpinya laarin oko ati aya atipe kinni aburu ti o wa nibi ki onpinya sele laarin oko ati aya.

Image

Idajọ Ibura laarin ọkọ ati iyawo (Al-Li’aanu) - (Èdè Yorùbá)

Ibanisọrọ yii da lori igbesẹ ti Islam fẹ ki Ọkọ iyawo gbe ti o ba se akiyesi pe iyawo rẹ nrin irinkurin, ti o si tun nse afihan bi Islam ti se idaabobo fun awọn obinrin kuro nibi abuku irọ Sina.