×
Image

Pataki Oro Omode ninu Islam - (Èdè Yorùbá)

Khutba yi da lori oro nipa awon omode ati bi won ti se Pataki ni awujo. Oniwaasi fi oro yi se khutuba ni ibamu pelu ojo ti orile-ede Nigeria mu gege bii ojo awon ewe (omode). O si se alaye pupo nipa bi esin Islam ti se amojuto awon omode.

Image

Iyakuya Ọmọ, ki ni awọn okunfa rẹ - (Èdè Yorùbá)

Awọn idi tabi okunfa ti awọn ọmọ ni awujọ wa loni fi nya alaigbọran

Image

Awọn Ohun ti o maa njẹ ki ọmọ ya alaigbọran - (Èdè Yorùbá)

Diẹ ninu awọn okunfa ipanle, janduku ati aigbọran ti awọn ọmọ ya kalẹ si awujọ. Itẹsiwaju ninu alaye awọn okunfa ipanle pẹlu awọn ọna abayọ si awọn iwa buburu yii.

Image

Ẹran ikomọjade ati awọn idajọ ti o rọ mọ ọ - (Èdè Yorùbá)

Alaye ohun ti o njẹ ẹran ikomọjade ati awọn ẹri ti o tọka si i ninu Sunna. Alaye awọn idajọ ẹran ikomọjade pẹlu sisọ awọn majẹmu ti o rọ mọ ọ. Abala yii ni oludanilẹkọ ti jẹ ki a mọ boya a le se ẹran ikomọjade ni ọbẹ, ki a....