×
Image

Awọn asikiri ti a maa sọ ni owurọ ati aṣalẹ - (Èdè Yorùbá)

Awọn asikiri ti a maa sọ ni owurọ ati aṣalẹ

Image

Àwọn Sunnah Ànábì Àwọn ìrántí Ọlọ́hun tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́ - (Èdè Yorùbá)

Mó ń gbé síwájú rẹ, ìrẹ ọmọ-ìyá mi nínú ẹ̀sìn Islām, tí ó ń ka ìwé yìí; àwọn ìlànà Ànábì – kí ìkẹ́ àti ọlà Ọlọ́hun máa bá a – tí ó máa ń ṣe ní ojoojúmọ́ láti ìgbà tí ó bá ti jí, títí di ìgbà tí yóò sùn,....