×
A o gbọ ninu Idanilẹkọ yii nipa ipo ti Islam to obinrin si ati apọnle ti Ọlọhun se fun wọn bakannaa kinni itumọ hijaab, idi ti hijaab fi jẹ ọranyan, awọn inira ti nbẹ nibi sisi ara silẹ ati aburu sise agbere.