Idẹkun Wahala laarin Lọkọ-Laya -1
Alaye ni abala akọkọ Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Sisọ nipa pataki ati anfaani ti o wa nibi igbeyawo, (ii) Sise alaye awọn ojuse lati ọdọ ọkọ si iyawo rẹ, bẹẹ naa ni awọn ojuse lati ọdọ iyawo si ọkọ rẹ, (iii) Sise apejuwe oniranran ede-aiyede laarin lọkọ-laya.
Àwọn ìsọ̀rí
- Àwọn ẹ̀tọ́ lọ́kọláya << Ìgbéyàwó << Ẹbí << Agbọye ẹsin