×
1 - Ọrọ nipa Masiihu Dajjaal gẹgẹ bi Ojisẹ Olọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ti se apejuwe ati awọn iroyin rẹ fun wa. 2 - Agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere yii: Se Masiihu Dajjaal nsẹmi lọwọ lọwọ, Njẹ yoo bimọ, ilu wo ni yoo ti jade, ati wipe awọn ilu wo ni ko nii de.