Asigbọ lori Akoko Irun Jimọh
Idanilẹkọ yii se alaye ọrọ awọn onimimọ ti o da lori igba ti o yẹ ki a maa ki Irun Jimọh, ni idahun si asigbọye ẹsin eyi ti o n waye lati ọwọ ikọ awọn ọdọ Musulumi kan ti wọn ngbe Irun Jimọh duro ni aago mẹsan awurọ.
Àwọn ìsọ̀rí
- Ìdájọ́ irun << Irun << Àwọn ìjọsìn << Agbọye ẹsin