O je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, o tun ko eko onipokeji ni ile eko giga University of Ilorin. O je okan ninu awon olupepe si oju ona Olohun ni liana sunna, o si ni igbiyanju lori oro esin.
O je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ilu Madina, o si ni igbiyanju lori ipepe si esin ni ilana awon oni sunna.
O je akekojade ni ile eko giga Islamic University ni ile Niger Republic, O si ni igbiyanju lori ipepe si oju ona Olohun ni ilana Sunna.
Sheikh Sharafudeen Gbadebo: O je okan ninu awon olukekojade ni ile eko Islamic University ni ilu Madina, O ni igbiyanju lori titu awon iwe esin si ede Yoruba nigbati o n keko ni ilu Madina. O si je okan ninu awon olupepe si oju ona Olohun ni ilana Sunna ni....
O je omo akekojade ni ile eko giga Lagos State Polytechnic ni ilu Eko. O si je eniti o feran lati maa pepe si oju ona Islam. O je Muslumi tooto ni oju ona ti sunna.