×
Image

Pataki Alukuraani ati Titobi Rẹ - 1 - (Èdè Yorùbá)

Ninu apa kinni yi: (1) Oro nipa awọn orukọ, iroyin ati awọn ẹwa ti Ọlọhun fi se iroyin Alukuraani. (2) Awọn ọla ti nbẹ fun Alukuraani. (3) Awọn ẹkọ ti o wa fun kika Alukuraani ati ọla ti nbẹ fun Olumọ Alukuraani.

Image

Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni - (Èdè Yorùbá)

Ise ijosin eyi ti erusin Olohun yoo maa ni esan lori re naa ni eyi ti o ba je wipe onigbagbo ododo ti o si n tele ilana anabi Muhammad ni o se e, sugbon eyi ti o ba je ti alaigbagbo ofo ati adanu ni yoo je ere re.

Image

Pataki Alukuraani ati Titobi Rẹ - 2 - (Èdè Yorùbá)

Alaye awọn nkan ti o le ran Musulumi lọwọ lati jẹ Olumọ Alukuraani pelu ibeere ati idahun.

Image

Yiyapa Ilana Awọn Asiwaju Ninu Ẹsin Nibi Itumọ Alukurani jẹ Okunfa Isina - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori bi o ti je dandan fun Musulumi lati maa tele ilana awon asiwaju ninu esin papaajulo awon omoleyin ojise Olohun (Saabe) ati awon ti won tele won (Taabi’un) nigbati o ba fe mo itumo Alukurani Alaponle.