×
Image

Ola Ti O Nbe Nibi Irun Kiki Ati Awon Anfaani Re - (Èdè Yorùbá)

Oore ti o po pupo ni o wa nibi irun kiki fun Musulumi. Ohun ni ona ti o dara julo lati wa asunmo si odo Olohun, o si maa nse okunfa aforiji fun Musulumi, bakannaa ni o je oluranlowo fun erusin lati wo ogba idera (al-Jannah).

Image

Ipo Irun Ninu Islam - (Èdè Yorùbá)

Akosile yi so nipa bi irun kiki ti se pataki to ninu esin Islam, ohun ni origun ti o lola julo leyin ijeri mejeeji, ohun naa si ni ise ti erusin maa n se ti o loore julo leyin won.

Image

Pataki Alukuraani ati Titobi Rẹ - 2 - (Èdè Yorùbá)

Alaye awọn nkan ti o le ran Musulumi lọwọ lati jẹ Olumọ Alukuraani pelu ibeere ati idahun.

Image

Ajosepo Laarin Awon Musulumi ati Awon ti Won Kiise Musulumi - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa awon nkan kan, ninu won niyi: (1) Musulumi ni eni ti iwa daradara ti Islam pepe si ba han ni ara re. (2) Ninu ohun ti esin Islam pase re ni ki Musulumi maa se aponle gbogbo eniyan, eni ti o je Musulumi ati eni ti....

Image

Pataki Alukuraani ati Titobi Rẹ - 1 - (Èdè Yorùbá)

Ninu apa kinni yi: (1) Oro nipa awọn orukọ, iroyin ati awọn ẹwa ti Ọlọhun fi se iroyin Alukuraani. (2) Awọn ọla ti nbẹ fun Alukuraani. (3) Awọn ẹkọ ti o wa fun kika Alukuraani ati ọla ti nbẹ fun Olumọ Alukuraani.

Image

Ninu Awon Eko Irinajo fun Ise Haj Tabi Umrah - (Èdè Yorùbá)

Wiwa ojurere Olohun, kiko awon ese sile, siso enu aala Olohun, didunni mo iranti Olohun ati beebee lo ni awon eko ti akosile yi so nipa won. Eleyi si ni die ninu awon ojuse Musulumi ti o ba gbero lati se irinajo fun ise Haj tabi Umrah.