×
Image

Ibẹru Ọlọhun ninu Irun kiki - (Èdè Yorùbá)

Awọn koko idanilẹkọ yii: (1) Alaye itumọ ibẹru Ọlọhun ninu irun kiki pẹlu apejuwe rẹ nibi isesi awọn ẹni-isaaju ti wọn jẹ ẹni-rere. (2) Itaniji si awọn isesi kan ti ko lẹtọ ninu irun. (3) Awọn ohun ti o le se okunfa ibẹru Ọlọhun ninu irun.

Image

Iwa Olojumeji ( Nifaak ) - (Èdè Yorùbá)

Itumọ iwa olojumeji (Nifaak) pẹlu idajọ rẹ ninu ofin Shariah, ati wipe iyatọ wo ni nbẹ ninu ọna meji ti Nifaak pin si.

Image

Itumọ Gbigbarale Ọlọhun ati awon Asise ti o n sẹlẹ nibẹ - (Èdè Yorùbá)

Itumọ Gbigbarale Ọlọhun pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah ati wipe se gbigbarale Ọlọhun tumọ si aajo sise?

Image

Ninu Apẹẹrẹ Opin Aye Ẹranko Nla ti yoo jade - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii jẹ ki a mọ Iru ẹranko, igba ati wipe ibo ni ẹranko naa yoo ti jade ni opin aye

Image

Ninu Apẹẹrẹ Opin Aye ni Eefin ti yoo jade - (Èdè Yorùbá)

Alaye lori eefin nla kan ti yoo bo aye kan pẹlu aburu eefin naa.

Image

Ninu Apẹẹrẹ Opin Aye Jijade Yaajuuj ati Maajuuj - (Èdè Yorùbá)

Sise apejuwe aburu yaajuuja ati maajuuja pẹlu ẹri lori rẹ lati inu Alukuraani ati Sunnah.

Image

Ninu Apẹẹrẹ Opin Aye Sisọkalẹ Anọbi Isa [ Ọla Ọlọhun ki o maa ba a ] - (Èdè Yorùbá)

Apejuwe bi Anabi Isa [Ọla Ọlọhun ki o maa ba a] yoo se sọkalẹ nigbati aye ba n lọ si opin pẹlu ẹri rẹ lati inu Alukuraani, ẹgbawa hadisi ati ọrọ awọn aafa onimimọ.

Image

Ọna Abayọ lọwọ Aburu Masiihu Dajjaal - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹko yii kun kẹkẹ fun awọn ọna abayọ kuro nibi aburu Masiihu Dajjaal

Image

Ninu Awọn Apẹẹrẹ Ọjọ Ikẹhin - Jijade Masiihu Dajjaal - (Èdè Yorùbá)

1 - Ọrọ nipa Masiihu Dajjaal gẹgẹ bi Ojisẹ Olọhun [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ti se apejuwe ati awọn iroyin rẹ fun wa. 2 - Agbegbe yii pese idahun si awọn ibeere yii: Se Masiihu Dajjaal nsẹmi lọwọ lọwọ, Njẹ yoo bimọ, ilu wo ni....

Image

Ninu Awọn Apẹẹrẹ Ọjọ Ikẹhin - Jijade Mahdi - (Èdè Yorùbá)

Ẹkunrẹrẹ alaye lori awọn orukọ pẹlu awọn iroyin Mahdi naa

Image

Awọn Amin Opin Aye - (Èdè Yorùbá)

(i) Awọn orukọ ti Ọjọ Ikẹhin njẹ, (ii) Igba ti aye yoo parẹ, ati wipe bawo ni o se sunmọ tabi jinna to.

Image

Igbaradi fun Ọjọ Ikẹhin - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ lori bi o se yẹ ki a maa se ipalẹmọ fun ọjọ igbende tiise ọjọ ikẹhin