×
Image

( Imura Obinrin ti Islam pa lasẹ ( Al-hijab - (Èdè Yorùbá)

Alaye lẹkunrẹrẹ nipa ọsọ obinrin ati ọrọ lori ohun ti o njẹ Hijaabu.

Image

Aburu Iwa Agbere ( Sina ) - 2 - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ nipa awọn okunfa iwa agbere (sina) ati idahun si awọn ibeere.

Image

Eko nipa Odun Itunu Aawe - (Èdè Yorùbá)

Olohun se ipari aawe ati ojo kewa osu Dhul-hijja ni odun fun awa Musulumi. Ibani soro yi n so nipa awon eko ti Islam ko wa nipa odun aawe. Ninu re ni ki Musulumi wo aso ti o dara ti o si wuyi ni ojo odun lati gbe ojo yi....

Image

Idẹkun Wahala laarin Lọkọ-Laya -3 - (Èdè Yorùbá)

Eyi ni abala idahun si awọn ibeere ti o jẹyọ lati ibi idanilẹkọ yii.

Image

Aburu Iwa Agbere ( Sina ) - 1 - (Èdè Yorùbá)

"[1] Alaye ohun ti o njẹ iwa agbere ati wipe isẹ buburu ti Ọlọhun korira ni. [2] Diẹ ninu awọn oniranran aburu ti o rọ mọ iwa agbere.".

Image

Idẹkun Wahala laarin Lọkọ-Laya -2 - (Èdè Yorùbá)

Abala yii sọ nipa awọn ọna mẹrin ti ede-aiyede ma ngba wa laarin lọkọ-laya, oludanilẹkọ si tun se alaye awọn igbesẹ ti Islam fẹ ki a gbe nigbati ede-aiyede ba waye laarin lọkọ-laya.

Image

Idẹkun Wahala laarin Lọkọ-Laya -1 - (Èdè Yorùbá)

Alaye ni abala akọkọ Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Sisọ nipa pataki ati anfaani ti o wa nibi igbeyawo, (ii) Sise alaye awọn ojuse lati ọdọ ọkọ si iyawo rẹ, bẹẹ naa ni awọn ojuse lati ọdọ iyawo si ọkọ rẹ, (iii) Sise apejuwe oniranran ede-aiyede laarin....

Image

Iha ti Islam ko si Imo- 3 - (Èdè Yorùbá)

Abala yii ni o gbẹyin idanilẹkọ yii ti o si kun kẹkẹ fun awọn ibeere pẹlu awọn idahun wọn.

Image

Iha ti Islam ko si Imo- 2 - (Èdè Yorùbá)

Oro waye ni apa yii lori awọn orisirisi ẹkọ ti o yẹ ki a ni akolekan rẹ lori imọ tabi ẹkọ ti a nwa, ti abala akọkọ ninu ibeere ati idahun si gbẹyin rẹ .

Image

Iha ti Islam ko si Imo- 1 - (Èdè Yorùbá)

Koko idanileko yii: (1) Awọn ẹsẹ Alukuraani ti nsọ nipa pataki Imọ ati awọn Onimimọ. (2) Alaye iru awọn imọ ti o le se wa ni anfaani ati eyi ti ko le mu anfaani kankan wa fun wa. (3) pataki wiwa imọ ẹsin pẹlu awọn nkan ti a gbọdọ sọ....

Image

Dida Ebi Po - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro se alaye ohun ti o nje ebi, o si se alaye bakannaa bi o se ye ki eniyan maa da ebi re po. O tun se afikun anfaani ti o wa nibi ki eniyan maa da ebi po ati ijiya ti o wa nibi ki eniyan maa ja okun....

Image

Itoju Awon Arun ni Ilana Islam - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa awon ona iwosan ninu Islam. Oniwaasi so wipe awon aisan ti o maa nse awon eniyan pin si meji: aisan emin ati aisan ara. O si so wipe iso ti o dara julo nibi gbogbo arun naa ni iberu Olohun ati gbigbe ara le E. Lehinnaa,....