×
Image

Idajo Sise Ise Ode ninu Islam - 3 - (Èdè Yorùbá)

Ninu apa keta yi olubanisoro se alaye awon asise ti awon ode maa nse yala asise ti o ropo mo adiokan tabi eyi ti o ropo mo ise sise.

Image

Oro Nipa Awon Alujannu - 2 - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro tun se alaye nipa bi awon alujannu se maa nlo awon eniyan ti won ba gbe ara won si ipo eniti won yoo maa ke pe ti won yoo si maa gbe aworan won wo lati fi so awon eniyan nu. Ni ipari, olubanisoro yi so nipa awon ona....

Image

Ọrọ Nipa Hijaab fun Obinrin Musulumi - 2/ 4 - (Èdè Yorùbá)

Awọn ẹri lati inu Alukuraani ati Sunah lori wipe ọranyan ni Jẹlbaab lilo, apejuwe bi o se yẹ ki Jẹlbaab ri ati majẹmu rẹ.

Image

Idajo Sise Ise Ode ninu Islam - 2 - (Èdè Yorùbá)

Ninu apa yi: (1) Oro nipa awon irinse ti eniyan fi le se ode. (2) Oro nipa awon eranko ti ko leto ki Musulumi je. (3) Die ninu awon eko sise ise ode.

Image

Oro Nipa Awon Alujannu - 1 - (Èdè Yorùbá)

Alaye ni ekunrere wa ninu ibanisoro yi nipa awon al-jannu. Bibe awon al-jannu ninu imo ikoko ti Musulumi gbodo ni igbagbo si ni, o nbe ninu awon al-jannu yi onigbagbo ododo o si nbe ninu won eni ti o ko ti Olohun ti o je keferi. Olubanisoro tun toka awon....

Image

Ọrọ Nipa Hijaab fun Obinrin Musulumi - 1/ 4 - (Èdè Yorùbá)

A o gbọ ninu Idanilẹkọ yii nipa ipo ti Islam to obinrin si ati apọnle ti Ọlọhun se fun wọn bakannaa kinni itumọ hijaab, idi ti hijaab fi jẹ ọranyan, awọn inira ti nbẹ nibi sisi ara silẹ ati aburu sise agbere.

Image

Idajo Sise Ise Ode ninu Islam - 1 - (Èdè Yorùbá)

Oro ni soki nipa ise ode ninu Islam, olubanisoro bere oro re pelu alaye bi esin Islam se dasi gbogbo igbesi aye omo eniyan ati awon eda miran ti ko si fi ibikankan sile lai dasi.

Image

Esin Islam ni Ile Africa laarin Shariah ati Asa - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori awon asa ti Islam fi ara mo ati awon eyi ti ko fi ara mo ni odo awon eya Yoruba ati die ninu awon eya miran ni ile alawo dudu (Africa). Awon olubanisoro mejeeji si mu awon apeere asa naa wa, bakannaa ni won menu ba....

Image

Ola Osu Ramadan ati Ilana ti o to lori bibere Aawe nibe - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi se alaye ni ekunrere awon ola ti o n be fun osu Ramadan, ninu re si ni wipe Olohun daruko osu yi ninu Al-kurani ti ko si daruko osu miran leyin re. Ninu awon ola ti Olohun se fun osu yi ni wipe Olohun yoo pa ase wipe....

Image

Iwọ Awọn Alabagbe - 2/2 - (Èdè Yorùbá)

Apẹrẹ sise daadaa si alabagbe ẹni lati ọdọ awọn Sahabe Anabi ati awọn ẹni-rere isaaju ninu Islam.

Image

Iwọ Awọn Alabagbe -1/2 - (Èdè Yorùbá)

Itumọ alabagbe ati awọn ẹri lori bi o ti se pataki ki Musulumi maa se daadaa si alabagbe lati inu Alukuraani ati sunna.

Image

Idajo Dida ina sun Oku Omo Eniyan ninu Islam - 2 - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori idajo Islam lori ki won da ina sun oku omo eniyan, Olubanisoro mu eri wa ninu hadiisi ojise Olohun lori wipe omo eniyan ni aponle leyin iku re bi o ti ni aponle nigbati o wa ni aye. Haraam ni idajo ki won da ina sun....