×
Image

Ọranyan Aluwala ati Ohun ti o nba a jẹ - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa awọn ọranyan aluwala, ati awọn ohun ti a fẹ ki Musulumi se ninu aluwala ati awọn ohun ti o nba aluwala jẹ.

Image

Ọla ti o nbẹ fun Aluwala ati bi a ti se nse e - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori alaye bi a se nse aluwala ati awọn ẹsan (ọla) ti o nbẹ fun aluwala sise, bakannaa ọrọ nipa awọn ohun ti o nsọ aluwala di ọranyan fun musulumi.

Image

Bi a ti se nwẹ Iwẹ Ọranyan (Al-Guslu) - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ waye lori awọn nkan marun ti o maa nsọ iwẹ di dandan fun ni lati wẹ, alaye si tun waye ni soki lori bi a se le wẹ iwẹ naa.

Image

Musulumi ni mi - (Èdè Yorùbá)

Musulumi ni mi

Image

Alaye nipa Irun Jimoh ninu tira Buluugul-maraam - (Èdè Yorùbá)

2- Alaye lori awon idajo ti o sopo mo irun Jimoh, ninu won ni: (1) Asiko wo ni irun Jimoh maa n wole. (2) Onka wo ni o ye ki o pe ki a to le ki irun Jimoh. (3) Rakah melo ni Musulumi gbodo ba ki o to le....

Image

Sise Atẹgun lọsi ọdọ Ọlọhun Allah - (Èdè Yorùbá)

Alaye awọn ọna ti o tọ, ti Musulumi fi le maa se atẹgun lọ si ọdọ Ọlọhun Allah

Image

Gbigba Kadara gbo - (Èdè Yorùbá)

Akole yi so nipa bi o ti se je ojuse Musulumi ki o so enu aala Olohun nigba ti o ba n wa arisiki, ki o ma gba ona haraam ti Olohun ko fe lati fi wa oro. Ki o ma fi ibinu Olohun wa iyonu awon eniyan.

Image

Ninu Awon Iruju Jamaa Ahmadiyya (Qoodiyaaniyyah) - (Èdè Yorùbá)

1- Eleyi ni iforowero laarin Ijo Ahmadiyyah ati Ijo Tadomun Muslimeen lori wipe se Annabi Isa- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ku si ori igi agbelebu ni tabi ko ku, se won gbe gun Sanmo lo ni tabi o wa ni ibikan lori ile aye yii.....

Image

Ipo Irun Ninu Islam - (Èdè Yorùbá)

Akosile yi so nipa bi irun kiki ti se pataki to ninu esin Islam, ohun ni origun ti o lola julo leyin ijeri mejeeji, ohun naa si ni ise ti erusin maa n se ti o loore julo leyin won.

Image

Itosona Lori Asigbo Esin - (Èdè Yorùbá)

1- Ibanisoro yii da lori awon ona abayo si asigbo esin ti o gbaye kan laarin awon Musulumi. 2- Ibanisoro je afikun lori awon okunfa ati ona abayo si awon asigbo tabi aseju ninu esin.

Image

Ojise Aanu - (Èdè Yorùbá)

1- Oro lori koko ohun ti Olohun fi ran ojise Re Muhammad, iranse ni o je si gbogbo aye patapata. 2- Pelu bi o ti je wipe awon osebo fi inira kan ojise Olohun ni ilu Makka sibe sibe o tun fi aanu bawon lo ti ko si fi ibi....

Image

Majemu Pipe Eniyan kan ni Keferi - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yii da lori awon majemu ti a gbodo ri lara musulumi kan ki a to le pe ni Keferi, ti Olubanisoro si bere pelu nkan ti pipe Musulumi kan ni keferi tumo si ninu Islam.