×
Image

Itumọ Idamẹwaa Ikẹyin Ninu Al-Quraan Alapọnle - (Èdè Yorùbá)

Itumọ Idamẹwaa Ikẹyin Ninu Al-Quraan Alapọnle.

Image

Itumọ Suuratul-Asri ati diẹ ninu awọn Anfaani rẹ - (Èdè Yorùbá)

Awọn iroyin ti eniyan fi le moribọ kuro ninu ofo aye, awọn iroyin naa ni: (i) Igbagbọ to peye ninu Ọlọhun Allah, (ii) sise isẹ tọ igbagbọ, (iii) igbara ẹni ni iyanju sise daadaa, (iv) igbara ẹni ni iyanju sise suuru.

Image

Alaye Itumo Aayah kẹtadinlaadọrun ninu Suuratul Bakọrah - (Èdè Yorùbá)

Itumọ aayah kẹtadinlaadọrun lati inu Suuratul Bakọrah eyi ti o da lori iroyin bi Ọlọhun Allah se se aranse fun Anọbi Isa ati bi awọn Yahuudi se tako igbedide Ojise Olohun Muhammad.

Image

Alaye Suratul Fatiha - (Èdè Yorùbá)

Eyi ni alaye Suratul Fatiha lati Aayah akoko titi de Aayah keta pelu awon eko l’oniranran.

Image

Alaye lori Aayah (23) ninu Suuratu Furkooni - (Èdè Yorùbá)

Ise ijosin eyi ti erusin Olohun yoo maa ni esan lori re naa ni eyi ti o ba je wipe onigbagbo ododo ti o si n tele ilana anabi Muhammad ni o se e, sugbon eyi ti o ba je ti alaigbagbo ofo ati adanu ni yoo je ere re.

Image

Alaye Aaya kẹjọ ati ẹkẹsan ninu Suuratul Mumtahinah - (Èdè Yorùbá)

Ohun ti o waye ninu ibanisọrọ yii: (1) Sise daadaa si aladugbo ti kiise Musulumi. (2) Ki ọmọ maa se daadaa si awọn obi rẹ mejeeji ti wọn kiise Musulumi.

Image

Yiyapa Ilana Awọn Asiwaju Ninu Ẹsin Nibi Itumọ Alukurani jẹ Okunfa Isina - (Èdè Yorùbá)

Ibanisoro yi da lori bi o ti je dandan fun Musulumi lati maa tele ilana awon asiwaju ninu esin papaajulo awon omoleyin ojise Olohun (Saabe) ati awon ti won tele won (Taabi’un) nigbati o ba fe mo itumo Alukurani Alaponle.

Image

Alaye itumo idamewa igbeyin ninu alukurani alaponle ni ede yoruba [agbekale ti ohun] - (Èdè Yorùbá)

Awon apo-iwe ti ohun fun kika idamewa igbeyin ninu alukurani alaponle, awon naa ni: eleekeji-din-logbon, eleekokan-din-logbon ati ogbon, pelu itumo re ni ede yoruba pelu ohun ti o dun, ti o wu eti gbo.

Image

Alaye Ibere Suratu Bakora - (Èdè Yorùbá)

Alaye die ninu awon Aayah ibere Suratu Bakora pelu alaye ekunrere lori itumo “Idaayah” ati awon nkan miran.