×
Image

Ilana Muhammad – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – nibi awọn ijọsin rẹ ati awọn ibaṣepọ rẹ ati awọn iwa rẹ - (Èdè Yorùbá)

Ilana Muhammad – ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – nibi awọn ijọsin rẹ ati awọn ibaṣepọ rẹ ati awọn iwa rẹ

Image

Ojise Olohun Muhammad Ike ni o je fun Gbogbo Aye - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro se alaye bi ojise Olohun anabi Muhammad se je ike fun gbogbo aye, Olohun lo ojise naa lati se agbega fun awon iwa rere O si loo lati pa awon iwa buburu re. Olohun si da ojise re ni eniti o pe ni eda ati ni iwa.

Image

Ojise Aanu - (Èdè Yorùbá)

1- Oro lori koko ohun ti Olohun fi ran ojise Re Muhammad, iranse ni o je si gbogbo aye patapata. 2- Pelu bi o ti je wipe awon osebo fi inira kan ojise Olohun ni ilu Makka sibe sibe o tun fi aanu bawon lo ti ko si fi ibi....

Image

Ibasepo Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- Pelu Awon Saabe re - 2 - (Èdè Yorùbá)

Apa keji yi so nipa awon nkan wonyi: (1) Awon eko ti o dara julo ti o wa nibi ibasepo Ojise Olohun pelu awon Saabe re. (2) Sise awon Musulumi ni ojukokoro sibi kikose Ojise Olohun nibi awon iwa re fun oore aye ati orun.

Image

Ibasepo Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- Pelu Awon Saabe re - 1 - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi je idahun fun awon ibeere wonyi: (1) Kinni paapaa itumo fiferan Ojise Olohun? (2) Kinni idi ti Olohun fi royin Ojise Re pelu iwa rere nibi ti O ti so wipe: {Dajudaju ire (Anabi) ni o ni iwa ti o dara julo}. (3) Tani eni ti o je....

Image

NJE A LE RI ANABI NI OJU ALA? - (Èdè Yorùbá)

Akosile yi da lori bi eniyan kan se le ri anabi wa Muhammad- ki ike ati ola Olohun maa ba a- ti yoo si mo wipe anabi gan an ni oun ri, bakannaa o se alaye bi o se je wipe awon eniyan kan maa n ri Esu [Shatani] ti....

Image

Ninu awọn Iwa Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a] - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori awọn Iwa Abiyì ti a le kọ ẹkọ rẹ lati ara Anọbi Muhammad [Ikẹ ati ola Ọlọhun ki o maa ba a]