×
Image

Lilo Sunna Laarin Aseju ati Aseeto Lodo Awon Odo - (Èdè Yorùbá)

Ibanisọrọ yii da lori sise aseju tabi aseeto ninu ẹsin eyi ti o wọpọ laarin awọn ọdọ, ti olubanisọrọ si jẹ ki a mọ awọn okunfa rẹ gẹgẹ bii: 1-Aini imọ ẹsin ti o kun to, 2-Agbọye odi lori ẹsin, 3-lilero aburu si awọn onimimọ, 4-Igbarata ẹsin, 5- Sisọ gbogbo....

Image

Ojuse Odo Lori Atunse Awujo - 2 - (Èdè Yorùbá)

Oniwaasi se afihan re wipe iyipada ko le waye laisi awon nkan wonyi: Alakoko: Agboye imo ijinle nipa esin Islam. Eleekeji: Wiwa awon imo ijinle ti awujo ni bukaata si. Eleeketa: Sise igbiyanju lati fi imo naa kede esin Islam.

Image

Ojuse Odo Lori Atunse Awujo - 1 - (Èdè Yorùbá)

Olubanisoro se alaye wipe imo nipa Olohun Allah ni eniyan maa fi n mo iyato laarin ohun ti o dara ati eyi ti ko dara, o si so wipe eniti o ba mo ohun ti o dara yato si eyi ti ko dara ni yoo le gbero ayipada ni awujo.