Ojuse Odo Lori Atunse Awujo - 2
Oniwaasi se afihan re wipe iyipada ko le waye laisi awon nkan wonyi: Alakoko: Agboye imo ijinle nipa esin Islam. Eleekeji: Wiwa awon imo ijinle ti awujo ni bukaata si. Eleeketa: Sise igbiyanju lati fi imo naa kede esin Islam.
Àwọn ìsọ̀rí
- Àwùjọ Musulumi << Ẹbí << Agbọye ẹsin
- Ọrọ tí ó jẹ mọ́ ọ̀dọ́ << Ẹbí << Agbọye ẹsin