Alaye nipa Irun Odun Mejeeji ninu tira Buluugul-maraam
1- Alaye lori Irun Ọdun mejeeji ati awọn ofin ti o rọ mọ aaye ikirun pẹlu awọn imura ti wọn fẹ ki a mu fun Irun ọdun.
3- Idanileko ni apa yi da lori awọn ẹwa khutuba Ojise Olohun- ike ati ola Olohun ki o maa ba a- ni ọjọ odun ati tita koko ọrọ lori wipe se o maa ngbe minbari lọ si aaye ikirun ni tabi wọn mọ pa si ibẹ.
Àwọn ìsọ̀rí
- Irun yídì méjèèjì << Irun àkígbọrẹ << Irun << Àwọn ìjọsìn << Agbọye ẹsin
- Ọdún << Awọn iṣẹlẹ igbadegba. << Ọlaju Islam
- Ọdún << Awọn iṣẹlẹ igbadegba. << Ọlaju Islam