×
Image

Idajọ biba Keferi kopa ninu Ọdun wọn - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yi sọ nipa itumọ biba awọn keferi kopa ninu ọdun wọn pẹlu awọn ẹri lorisirisi lori bi biba awọn keferi kopa ninu ọdun wọn se jẹ eewọ fun Musulumi.

Image

Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 2 - (Èdè Yorùbá)

Alaye lori awọn adadaalẹ pẹlu awọn isẹ oloore ti nbẹ ninu awọn osu oju ọrun: Osu Rọbiul-Awwal titi de Dhul Hijjah.

Image

Awọn Isẹ oloore ti Sharia pa lasẹ ninu Osu Oju Ọrun ati Adadasilẹ ti awọn Eniyan nse nibẹ 1 - (Èdè Yorùbá)

Awọn adadaalẹ pẹlu awọn isẹ oloore ti nbẹ ninu osu Muharram ati Osu Sọfar.

Image

Ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi kosi ninu Ẹsin Islam - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o sọ nipa bi sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi wa Muhammad se jẹ adadasilẹ ninu ẹsin, pẹlu awọn ẹri ti o rinlẹ.

Image

Idajọ Sise Ọjọ Ibi Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a] -3 - (Èdè Yorùbá)

Oludanilẹkọ sọ ni apa yii ọrọ awọn aafa ti wọn sọ wipe adadasilẹ sise ni ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a) pẹlu awọn ẹri ti wọn fi rinlẹ lori awọn ọrọ wọn.

Image

Idajọ Sise Ọjọ Ibi Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a] -2 - (Èdè Yorùbá)

Oludanilẹkọ sọ ni apa yii ọrọ awọn aafa ti wọn sọ wipe ko si laifi nibi sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a).

Image

Idajọ Sise Ọjọ Ibi Anabi Muhammad [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a] -1 - (Èdè Yorùbá)

Ọrọ nipa bi sise ajọdun ọjọ ibi Anabi (Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki maa ba a) se bẹrẹ.

Image

Idajọ sise Ayẹyẹ Ọjọ Ibi Anabi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] - (Èdè Yorùbá)

Awọn ẹri lori wipe adadasilẹ ninu ẹsin ni sise ayẹyẹ ọjọ ibi Anabi [Ikẹ ati ọla Ọlọhun ki o maa ba a] ati bi ayẹyẹ naa se bẹrẹ.

Image

Eko nipa Odun Itunu Aawe - (Èdè Yorùbá)

Olohun se ipari aawe ati ojo kewa osu Dhul-hijja ni odun fun awa Musulumi. Ibani soro yi n so nipa awon eko ti Islam ko wa nipa odun aawe. Ninu re ni ki Musulumi wo aso ti o dara ti o si wuyi ni ojo odun lati gbe ojo yi....

Image

Gbigba Aawe Ninu Gbogbo Awon Ojo Osu Rajab Ati Sha’baan - (Èdè Yorùbá)

Awon eniyan kan maa n gba aawe ninu gbogbo ojo osu Rajab at Sha’baan lehinnaa Ramadan, nje eri wa lori ohun ti won n se yi bi?