×
Image

Awọn ohun ti o yẹ ki musulumi o mọ, ki o si maa se ni Ọjọ jimoh. - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o sọ nipa pataki ọjọ jimọh ati awọn ohun ti ye ki Musulumi se nibẹ gẹgẹ bii iwẹ, lilo lọfinda oloorun didun ati bẹẹbẹẹ lọ.

Image

Idajo ki eniyan to ni iduro - (Èdè Yorùbá)

Fatwa yi so fun wa nipa bi o ti je wipe eniyan leto lati to ni iduro bi o tile je wipe ipile ni ki eniyan bere nigbati o ba fe to.

Image

Pataki Iranti Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o sọ nipa pataki iranti Ọlọhun pẹlu awọn ẹri lati inu Alukurani ati hadiisi.