×
Image

Awọn Ẹbọ sise ti apakan ninu awọn Musulumi ko fiye si - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ ti o se alaye siso gbekude mọ ara, gbere sinsin ati nkan miran ti o fi ara pẹẹ lara awọn ohun ti o jẹ mọ ẹbọ sise.

Image

Ẹbọ sise: Itumọ rẹ ati Awọn Ipin rẹ - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yi da lori wipe idakeji ẹbọ sise ni sise Ọlọhun Allah ni aaso tabi gbigba A ni okan soso pẹlu ẹri Alukuraani ati ẹgbawa hadisi. Alaye tẹsiwaju nipa itumọ ẹbọ sise pẹlu awọn ọna ti ẹbọ sise pin si.

Image

Ibura Pẹlu Nkan Miran Ti o Yatọ si Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Alaye nipa idajọ ibura pẹlu nkan miran ti o yatọ si Ọlọhun Allah, nigbati o maa n jẹ ẹbọ kekere ati nigbati o maa n jẹ ẹbọ nla.

Image

Idajọ Ẹsin lori Rukiya, Oogun Ifẹ ati Gbekude lilo - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ yii da lori awọn koko wọnyii: (i) Iha ti ẹsin ko si Rukiya, Oogun ifẹ ati Gbekude lilo, (ii) Idajọ awọn nkan mẹtẹẹta yii, (iii) Majẹmu Rukiya, (iv) Idajọ wiwe ayah Alukuraani ati dide mọ ọrun, (v) Diẹ ninu awọn Rukiya ti a le fi se isọ fun alaarẹ,....

Image

Awọn Asa ti o ba Islam mu ati eyi ti o tako Islam - (Èdè Yorùbá)

Waasi oniyebiye ti o sọ nipa awọn asa ti o dara ti ẹsin Islam kin lẹyin, bakannaa awọn asa ti ko dara ti Islam kọ fun awa Musulumi.

Image

Asa ati Ẹsin - (Èdè Yorùbá)

Idanilẹkọ ti o n se alaye awọn nkan ti o n ba ẹsin jẹ mọ Musulumi lọwọ ti apa kan ninu awọn eniyan si n pe ni asa.

Image

Awọn Nkan ti Apa kan Ninu Awọn Musulumi fi maa n bura Yatọ si Ọlọhun - (Èdè Yorùbá)

Akọsilẹ ti o sọ diẹ ninu awọn nkan ti apa kan ninu awọn alaimọkan Musulumi fi maa n se ibura ti o si lodi si ilana ẹsin Islam.

Image

Esin Islam ati Asa - (Èdè Yorùbá)

Waasi yi so nipa asa ati esin Islam, olubanisoro pin asa si meji: eyi ti o dara ati eyi ti ko dara. Lehinnaa o so wipe esin Islam fi awon eniyan sile lori asa ti won nse ti o dara o si ko fun won nibi eyi ti ko dara....