Sise Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ

أعرض المحتوى باللغة العربية anchor

translation Kiko iwe : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
1

Sise Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ - 2

25.6 MB MP3
2

Sise Ọlọhun ni Ọkan Soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ - 1

26.3 MB MP3

1- Awọn akori ọrọ ti o jẹyọ ni abala yii ni wọnyii: (i).Itumọ sise Ọlọhun ni Ọkan soso nibi Awọn Orukọ Rẹ ati Iroyin Rẹ. (ii). Alaye lori awọn ti wọn lodi si Sunna nibi ilana yii. 2- Alaye nipa ilana awọn ti won tẹle Sunna nibi orukọ Ọlọhun ati awọn iroyin Rẹ.