Awọn Aisedeede ti o maa nsẹlẹ pupọ lori Irun
أعرض المحتوى باللغة العربية
Pataki irun kiki ati wipe ohun ni akọkọ ohun ti Musulumi yoo se isiro rẹ ni ọjọ ajinde. Diẹ ninu awọn aisedeede naa gẹgẹ bii: aifarabalẹ, wiwo ọtun wosi lori irun ati bẹẹbẹẹ lọ.