Ẹran ikomọjade ati awọn idajọ ti o rọ mọ ọ

أعرض المحتوى باللغة العربية anchor

translation Kiko iwe : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
1

Ẹran ikomọjade ati awọn idajọ ti o rọ mọ ọ - 3

26.8 MB MP3
2

Ẹran ikomọjade ati awọn idajọ ti o rọ mọ ọ - 2

26.8 MB MP3
3

Ẹran ikomọjade ati awọn idajọ ti o rọ mọ ọ - 1

27.2 MB MP3

Alaye ohun ti o njẹ ẹran ikomọjade ati awọn ẹri ti o tọka si i ninu Sunna. Alaye awọn idajọ ẹran ikomọjade pẹlu sisọ awọn majẹmu ti o rọ mọ ọ. Abala yii ni oludanilẹkọ ti jẹ ki a mọ boya a le se ẹran ikomọjade ni ọbẹ, ki a pe awọn eniyan waa jẹ ẹ, tabi dandan ni ki a pin in ni tutu?