Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ

أعرض المحتوى باللغة العربية anchor

translation Kiko iwe : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
1

Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ - 2

26.5 MB MP3
2

Iroyin Alujannah ati Awọn Olugbe rẹ - 1

27.3 MB MP3

1- Idanilẹkọ yii sọ nipa oniranran apejuwe nipa ibugbe Alujannah gẹgẹ bi awọn apejuwe yii se wa lati inu Alukuraani ati Sunnah Ojisẹ Ọlọhun. 2- Alaye lori awọn isẹ ti o maa nse okunfa wiwọ Alujannah gẹgẹ bi Ọlọhun ti se se iroyin rẹ lati inu Alukuraani ati Sunna.