Iroyin Ina ati Awọn ohun ti ngbe Eniyan wọ ọ

أعرض المحتوى باللغة العربية anchor

translation Kiko iwe : Abdur Rahman Muhammadul Awwal
1

Iroyin Ina ati Awọn ohun ti ngbe Eniyan wọ ọ - 2

26.1 MB MP3
2

Iroyin Ina ati Awọn ohun ti ngbe Eniyan wọ ọ - 1

26.2 MB MP3

1- Idanilẹkọ ni agbegbe yii sọ awọn ayọka Alukuraani ati ẹgbawa hadisi ti nse apejuwe bi Ina se ri. 2- Alaye awọn okunfa ti o maa nmu eniyan wọ Ina, awọn okunfa yii pin si meji: (1) Okunfa ti o maa nmu eniyan bẹ ninu Ina lọ gbere, (2) okunfa ti o maa nmu Musulumi bẹ ninu Ina fun igba diẹ.