translation Kiko iwe : Isa Akindele Solahudeen
1

Awon Eko Pataki Nibi Ogun Khandak

38.9 MB MP3

Alaye ohun ti o se okunfa ogun yii ati awon isele ti o waye nibi sise ipalemo fun ogun naa eyi ti o je eri ododo lori wipe Annabi Muhammad ojise Olohun ni. Alaye si tun waye lori aranse ti Olohun se fun ojise Re ninu ogun naa.